1 Ọba 10:8 BMY

8 Báwo ni inú àwọn ènìyàn rẹ yóò ṣe dùn tó! Báwo ni inú dídùn àwọn ìránṣẹ́ rẹ, tí wọ́n ń dúró níwájú rẹ nígbà gbogbo, tí wọ́n sì ń gbọ́ ọgbọ́n rẹ!

Ka pipe ipin 1 Ọba 10

Wo 1 Ọba 10:8 ni o tọ