1 Ọba 21:10 BMY

10 Ṣùgbọ́n kí ẹ fi ènìyàn méjì, ẹni búburú ṣíwájú rẹ̀ láti jẹ́rìí pa á wí pé, ó bú Ọlọ́run àti ọba. Nígbà náà ni kí ẹ mú u jáde, kí ẹ sì sọ ọ́ ní òkúta pa.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:10 ni o tọ