2 Sámúẹ́lì 1:15 BMY

15 Nígbà náà Dáfídì pe ọ̀kan nínú ọkùnrin, ó sì wí pé, “Lọ, gbé e lulẹ̀!” Nígbà náà ó gbé e lulẹ̀, ó sì kú.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 1

Wo 2 Sámúẹ́lì 1:15 ni o tọ