2 Sámúẹ́lì 10:9 BMY

9 Nígbà tí Jóábù sì ríi pé ogun náà dojú kọ òun níwájú àti lẹ́yìn, ó sì yàn nínú gbogbo àwọn akíkanjú ọkùnrin ní Ísírẹ́lì, ó sì tẹ́ ogun kọjú sí àwọn ará Síríà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 10

Wo 2 Sámúẹ́lì 10:9 ni o tọ