Deutarónómì 20:17 BMY

17 Pa wọ́n run pátapáta, àwọn ọmọ Hítì, ọmọ Ámórì, ọmọ Kénánì, ọmọ Pérísì, ọmọ Hífì, ọmọ Jébúsì gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti pa á láṣẹ fún ọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 20

Wo Deutarónómì 20:17 ni o tọ