Ékísódù 32:31 BMY

31 Bẹ́ẹ̀ ni Mósè padà tọ Olúwa lọ, ó sì wí pé, “Yé, kí ni ẹ̀ṣẹ̀ ńlá tí àwọn ènìyàn ti dá yìí! Wọ́n ti ṣe òrìsà wúrà fún ara wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 32

Wo Ékísódù 32:31 ni o tọ