Ísíkẹ́lì 10:19 BMY

19 Àwọn kérúbù gbé ìyẹ́ wọn sókè, wọ́n sì fò kúrò nílẹ̀ lójú mi, wọ́n sì lọ pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ wọn lẹ́ẹ̀kan náà. Wọ́n dúró níbi ìlẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà ìlà-oòrùn ilé Olúwa, ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì sì wà lórí wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:19 ni o tọ