Ísíkẹ́lì 10:3 BMY

3 Àwọn kérúbù dúró sí apá gúúsù tẹ́ḿpìlì nígbà tí ọkùnrin náà wọlé, ìkùukùu sì bo inú àgbàlá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:3 ni o tọ