Jeremáyà 12:1 BMY

1 Olúwa, olódodo ni ọ́ nígbàkúgbà,nígbà tí mo mú ẹjọ́ kan tọ̀ ọ́ wá.Síbẹ̀ èmi yóò bá ọ sọ̀rọ̀ nípa òdodo rẹ.Èéṣe tí ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú fi ń ṣe déédéé?Èéṣe tí gbogbo àwọn aláìsòdodo sì ń gbé ní ìrọ̀rùn?

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:1 ni o tọ