Jeremáyà 23:25 BMY

25 “Mo ti gbọ gbogbo ohun tí àwọn wòlíì èké tí ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní orúkọ mi ń sọ. Wọ́n sọ wí pé, ‘Mo lá àlá! Mo lá àlá!’

Ka pipe ipin Jeremáyà 23

Wo Jeremáyà 23:25 ni o tọ