Jeremáyà 25:14 BMY

14 Àwọn fúnra wọn yóò sì sin orílẹ̀ èdè púpọ̀ àti àwọn Ọba ńlá. Èmi yóò sì sán fún oníkálukú gẹ́gẹ́ bí ìṣe àti iṣẹ́ ọwọ́ wọn.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:14 ni o tọ