Léfítíkù 26:13 BMY

13 Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín tí ó mú yín jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì: kí ẹ̀yin má baà jẹ́ ẹrú fún wọn mọ́. Mo sì já ìdè yín: mo sì mú kí ẹ̀yin máa rìn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí a gbé lórí sókè.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:13 ni o tọ