Nọ́ḿbà 13:29 BMY

29 Àwọn Ámálékì ń gbé ní ilẹ̀ Gúsù; àwọn ará Hítì, àwọn ará Jébúsì àti àwọn ará Ámórì ni wọ́n ń gbé ní orí òkè ilẹ̀ náà, àwọn ará Kénánì sì ń gbé ẹ̀bá òkun àti ní etí bèbè Jọ́dánì.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 13

Wo Nọ́ḿbà 13:29 ni o tọ