Nọ́ḿbà 26:4 BMY

4 “Ka iye àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ọmọ ogun (20) ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti paláṣẹ fún Mósè.”Èyí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí ó jáde láti Éjíbítì wá:

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:4 ni o tọ