Nọ́ḿbà 7:9 BMY

9 Ṣùgbọ́n Mósè kò fún àwọn ọmọ Kóhátì ní nǹkan kan nítorí pé èjìká wọn ni wọn yóò fi ru àwọn ohun mímọ́ èyí tí ó jẹ́ ojúṣe tiwọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:9 ni o tọ