Òwe 11:2 BMY

2 Nígbà tí ìgbéraga bá dé, nígbà náà ni ìdójútì déṣùgbọ́n, pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ ni ọgbọ́n ń wá.

Ka pipe ipin Òwe 11

Wo Òwe 11:2 ni o tọ