2 Jòhánù 1:7 BMY

7 Nítorí ẹlẹ́tàn púpọ̀ ti jáde wa sínú ayé, àwọn tí kò jẹ́wọ́ pé Jésù Kírísítì wá nínú ara. Èyí ni ẹlẹ̀tàn àti Aṣòdì sí Kírísítì.

Ka pipe ipin 2 Jòhánù 1

Wo 2 Jòhánù 1:7 ni o tọ