Gálátíà 1:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n nígbà tí ó wú Ọlọ́run ẹni tí ó yà mí sọ́tọ̀ láti inú ìyá mi wá, tí ó sì pé mi nípa oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:15 ni o tọ