Hosia 14:1 BM

1 Ẹ pada tọ OLUWA Ọlọrun yín lọ, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, nítorí pé ẹ ti kọsẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín.

Ka pipe ipin Hosia 14

Wo Hosia 14:1 ni o tọ