Kronika Keji 24:10 BM

10 Gbogbo àwọn ìjòyè ati gbogbo eniyan fi tayọ̀tayọ̀ mú owó orí wọn wá, wọ́n ń sọ ọ́ sinu àpótí náà títí tí ó fi kún.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:10 ni o tọ