7 Orúkọ wọn ni: Otini, Refaeli, Obedi, ati Elisabadi, ati àwọn arakunrin wọn, Elihu ati Semakaya, tí wọ́n jẹ́ alágbára eniyan.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 26
Wo Kronika Kinni 26:7 ni o tọ