Lefitiku 25:25 BM

25 Bí arakunrin rẹ bá di aláìní tí ó bá sì tà ninu ilẹ̀ rẹ̀, ọ̀kan ninu àwọn ẹbí rẹ̀ yóo dìde láti ra ohun tí ìbátan rẹ̀ tà pada.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:25 ni o tọ