Samuẹli Keji 17:24 BM

24 Nígbà tí Absalomu ati àwọn ọmọ Israẹli yóo fi ré odò Jọdani kọjá tán, Dafidi ti dé ìlú tí wọn ń pè ní Mahanaimu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:24 ni o tọ