Samuẹli Keji 18:27 BM

27 Ẹ̀ṣọ́ tún ní, “Ẹni tí ó ṣáájú tí mo rí yìí jọ Ahimaasi.”Ọba dáhùn pé, “Eniyan dáradára ni, ìròyìn ayọ̀ ni ó sì ń mú bọ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:27 ni o tọ