Samuẹli Keji 21:7 BM

7 Ṣugbọn nítorí majẹmu tí ó wà láàrin Dafidi ati Jonatani, Dafidi kò fi ọwọ́ kan Mẹfiboṣẹti, ọmọ Jonatani, ọmọ Saulu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:7 ni o tọ