Johanu Kinni 2:8 BM

8 Ṣugbọn ní ìdàkejì, òfin titun ni mò ń kọ si yín, èyí tí a rí òtítọ́ rẹ̀ ninu Jesu Kristi ati ninu yín, nítorí pé òkùnkùn ń kọjá lọ, ìmọ́lẹ̀ tòótọ́ sì ti ń tàn.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 2

Wo Johanu Kinni 2:8 ni o tọ