Luku 11:30 BM

30 Nítorí bí Jona ti di àmì fún àwọn ará Ninefe, bẹ́ẹ̀ gan-an ni Ọmọ-Eniyan yóo jẹ́ àmì fún ìran yìí.

Ka pipe ipin Luku 11

Wo Luku 11:30 ni o tọ