Romu 2:10 BM

10 Ṣugbọn yóo fi ògo, ọlá ati alaafia fún gbogbo àwọn tí ó ń ṣe rere. Àwọn Juu ni yóo kọ́kọ́ fún, lẹ́yìn náà yóo fún àwọn Giriki.

Ka pipe ipin Romu 2

Wo Romu 2:10 ni o tọ