Dan 12:13 YCE

13 Ṣugbọn iwọ ma ba ọ̀na rẹ lọ, titi opin yio fi de, iwọ o si simi, iwọ o si dide duro ni ipo rẹ ni ikẹhin ọjọ.

Ka pipe ipin Dan 12

Wo Dan 12:13 ni o tọ