Eks 32:10 YCE

10 Njẹ nisisiyi jọwọ mi jẹ, ki ibinu mi ki o gbona si wọn, ki emi ki o le pa wọn run: emi o si sọ iwọ di orilẹ-ède nla.

Ka pipe ipin Eks 32

Wo Eks 32:10 ni o tọ