Iṣe Apo 1:16 YCE

16 Ẹnyin ará, Iwe-mimọ́ kò le ṣe ki o má ṣẹ, ti Ẹmi Mimọ́ ti sọtẹlẹ lati ẹnu Dafidi niti Judasi, ti o ṣe amọ̀na fun awọn ti o mu Jesu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 1

Wo Iṣe Apo 1:16 ni o tọ