Hábákúkù 1:11 BMY

11 Nígbà náà ni inú rẹ̀ yóò yípadà,yóò sì rékọjá, yóò siṣẹ̀ ní kika agbára rẹ̀ yìí sí iṣẹ́ òrìṣà rẹ̀.”

Ka pipe ipin Hábákúkù 1

Wo Hábákúkù 1:11 ni o tọ