Hábákúkù 1:16 BMY

16 Nítorí náà, ó rúbọ sí àwọ̀n rẹ̀,ó sì ń ṣun tùràrí fún àwọ̀n-ńlá rẹ̀nítorí pẹ̀lú àwọ̀n rẹ̀ ni ó fí ń gbé ní ìgbádùntí ó sì ń gbádùn pẹ̀lú oúnjẹ tí ó bá wù ú.

Ka pipe ipin Hábákúkù 1

Wo Hábákúkù 1:16 ni o tọ