Hábákúkù 3:16 BMY

16 Mo gbọ́, ọkàn mi sì wárìrì,ètè mi sì gbọ̀n sí ìró náà;ìbàjẹ́ sì wọ inú egungun mi lọ,ẹ̀sẹ̀ mi sì wárìrì,mo dúró ni ìdákẹ́jẹ́ fún ọjọ́ ìdààmúláti de sórí àwọn ènìyàn tó ń dojúkọ wá.

Ka pipe ipin Hábákúkù 3

Wo Hábákúkù 3:16 ni o tọ