Náhúmù 1:12 BMY

12 Báyìí ni Olúwa wí:“Bí wọ́n tilẹ̀ pé, tí wọ́n sì pọ̀ níye,Ṣùgbọ́n, báyìí ní a ó ké wọn lulẹ̀,nígbà tí òun ó bá kọ́já.Bí mo tilẹ̀ ti pọ́n ọ lójú ìwọ Júdà, èmi kì yóò pọ́n ọ lójú mọ́.

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:12 ni o tọ