Náhúmù 1:14 BMY

14 Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Nínéfè:“Ìwọ kì yóò ni irú ọmọ láti máa jẹ́ orúkọ rẹ mọ́,Èmi yóò pa ère fínfín àti ère dídà runtí ó wà nínú tẹ́ḿpílì àwọn ọlọ́run rẹ.Èmi yóò wa ibojì rẹ,nítorí ẹ̀gbin ni ìwọ.”

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:14 ni o tọ