1 Tẹsalóníkà 1:6 BMY

6 Tó bẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin pàápàá di aláwòkọ́ṣe wa àti ti Olúwa, ìdí ni pé, ẹ gba ẹ̀rí náà láti ọwọ́ Ẹ̀mi Mímọ́ pẹ̀lú ayọ̀ bí o tilẹ̀ jẹ́ pé, ó mú wàhálà àti ìbànújẹ́ wá fún yín.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 1

Wo 1 Tẹsalóníkà 1:6 ni o tọ