1 Tẹsalóníkà 2:15 BMY

15 àwọn tí wọ́n pa Jésù Olúwa àti àwọn wòlíì, tí wọ́n sì tì wa jáde. Wọn kò ṣe èyí tí ó wu Ọlọ́run, wọ́n sì ṣe lòdì sí gbogbo ènìyàn

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 2

Wo 1 Tẹsalóníkà 2:15 ni o tọ