1 Tẹsalóníkà 2:19 BMY

19 Kí ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, tàbí adé wa nínú èyí tí a ó sògo níwájú Jésù Olúwa nígbà tí òun bá dé? Ṣé ẹ̀yin kọ ní?

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 2

Wo 1 Tẹsalóníkà 2:19 ni o tọ