1 Tẹsalóníkà 3:10 BMY

10 Nítorí pé àwa ń gbàdúrà fún un yín lọ̀sán-án àti lóru. Èyí yóò ràn wá lọ́wọ́ láti se àtúnṣe ibi tí ìgbàgbọ́ yín bá kù sí.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 3

Wo 1 Tẹsalóníkà 3:10 ni o tọ