1 Tẹsalóníkà 3:12 BMY

12 A sì béérè pé, kí Ọlọ́run ràn yín lọ́wọ́ tó bẹ́ẹ̀ tí ìfẹ́ yín yóò fi gbòòrò tí yóò sì ṣàn kan olúkúlùkù yín. Èyí yóò jẹ́ àpẹrẹ gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ àwa náà se sàn kan ẹ̀yin náà.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 3

Wo 1 Tẹsalóníkà 3:12 ni o tọ