1 Tẹsalóníkà 3:2 BMY

2 Mo sì rán Tímótíù, arákùnrin àti alábáṣiṣẹ́ pọ̀ wá, láti bẹ̀ yín wò. Mo rán an láti fún ìgbàgbọ́ yín lágbára àti láti mú yín lọ́kà le; àti kí ó má sì ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú, nínú ìṣòro tí ẹ ń là kọjá.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 3

Wo 1 Tẹsalóníkà 3:2 ni o tọ