1 Tẹsalóníkà 3:7 BMY

7 Nítorí náà, ẹ̀yin ará, inú wá dùn jọjọ nínú gbogbo ìyọnu àti ìjìyà wa níbí nítorí pé àwa mọ̀ nísinsinyìí pé, ẹ̀yin sì dúró gbọn-ingbọn-in fún Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 3

Wo 1 Tẹsalóníkà 3:7 ni o tọ