1 Tẹsalóníkà 5:13 BMY

13 Ẹ bu ọlá fún wọn gidigidi nínú ìfẹ́, nítorí iṣẹ́ wọn. Ẹ sì máa wà ni àlàáfíà láàrin ara yín.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 5

Wo 1 Tẹsalóníkà 5:13 ni o tọ