1 Tẹsalóníkà 5:3 BMY

3 Ní àkókò gan an tí àwọn ènìyàn yóò máa wí pé, “Àláfíà àti àbò,” nígbà náà ni ìparun òjijì yóò dé sórí wọn gẹ́gẹ́ bí ìrọbí obìnrin tí ó lóyún, wọn kò sí rí ibi ààbò láti sá sí.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 5

Wo 1 Tẹsalóníkà 5:3 ni o tọ