1 Tímótíù 1:10 BMY

10 fún àwọn àgbèrè, fún àwọn aláyídà, fún àwọn onísòwò-ẹrú, fún àwọn èké, fún àwọn abúra èké, àti bí ohun mìíràn bá wà tí ó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ó yè kooro.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:10 ni o tọ