1 Tímótíù 2:7 BMY

7 Nítorí èyí tí a yàn mi ṣe oníwàásù, Àpósítélì—òtítọ́ ni èmi ń sọ, èmi kò ṣèké olùkọ́ àwọn aláìkọlà nínú ìgbàgbọ́ àti òtítọ́.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 2

Wo 1 Tímótíù 2:7 ni o tọ