1 Tímótíù 3:13 BMY

13 Nítorí àwọn tí ó lo ipò díákónì dáradára ra ipò rere fún ara wọn, àti ìgboyà púpọ̀ nínú ìgbàgbọ́ tí ń bẹ nínú Kírísítì Jésù.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:13 ni o tọ