1 Tímótíù 3:2 BMY

2 Ǹjẹ́ Bíṣọ́ọ̀bù yẹ kí ó jẹ́ aláìlẹ́gàn, ọkọ aya kan, olùsọ̀ràn, aláìrékọjá, oníwà yíyẹ, olùfẹ́ àlejò ṣíṣe, ẹni tí ó lè ṣe olùkọ́.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:2 ni o tọ