1 Tímótíù 3:5 BMY

5 Ṣùgbọ́n bí ènìyàn kò bá mọ̀ bí a ti ń ṣe ìkáwọ́ ilé ara rẹ̀, òun ó há ti ṣe lè tọ́jú ìjọ Ọlọ́run?

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:5 ni o tọ